Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ àwọn mìíràn wí pé, “Àwa ní láti yá owó láti san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba lórí àwọn oko wa àti àwọn ọgbà àjàrà wa.

Ka pipe ipin Nehemáyà 5

Wo Nehemáyà 5:4 ni o tọ