Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn mìíràn wí pé, “Àwa ti fi oko wa ọgbà àjàrà wa àti ilé wa dógò kí àwa kí ó lè rí oúnjẹ (ọkà) ní àkókò ìyàn.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 5

Wo Nehemáyà 5:3 ni o tọ