Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn Júù tí ó ń gbé ní ẹ̀gbẹ́ẹ wọn wá sọ fún wa ní ìgbà mẹ́wàá pé, “Ibikíbi tí ẹ̀yin bá padà sí, wọn yóò kọ lù wá.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:12 ni o tọ