Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ọ̀ta wa wí pé, “Kí wọn tó mọ̀ tàbí kí wọn tó rí wa, àwa yóò ti dé àárin wọn, a ó sì pa wọ́n, a ó sì dá iṣẹ́ náà dúró.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:11 ni o tọ