Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Úsíélì ọmọ Hariháyà, ọ̀kan lára àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà, tún ṣe àtúnṣe èyí tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀; àti Hananíyà, ọ̀kan lára awọn tí ó ń ṣe tùràrí, tún ṣe àtúnṣe èyí tí ó tún tẹ̀lé e. Wọ́n mú Jérúsálẹ́mù padà bọ̀ sípò títí dé Odi Gbígbòòrò.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:8 ni o tọ