Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 3:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn rẹ̀ ni, Hananáyà ọmọ Ṣelemáyà, àti Hánúnì ọmọ ẹ̀kẹfà Ṣáláfì, tún apá ibòmíràn ṣe. Lẹ́yìn wọn ni, Mésúlámù ọmọ Berekáyà tún ọ̀kánkán ibùgbé e rẹ̀ ṣe.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:30 ni o tọ