Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibodè Àfonífojì ni Hánúnì àti àwọn ará Ṣánóà tún mọ. Wọ́n tún-un kọ́ wọ́n ri àwọn ìlẹ̀kùn àti àwọn ide rẹ̀ sí ààyè rẹ̀. Wọ́n sì tún tún ẹgbẹ̀rún-ún kan ìgbọ̀nwọ odi mọ títí dé ẹnu ibodè ààtàn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:13 ni o tọ