Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni ọba béèrè lọ́wọ́ mi pé “Èéṣe tí ojú rẹ fi fàro nígbà tí kò rẹ̀ ọ́? Èyí kì í ṣe ohun mìíràn bí kò ṣe ìbànújẹ́ ọkàn”Ẹ̀rù bà mí gidigidi,

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:2 ni o tọ