Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 13:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀kan lára àwọn ọmọ Jóíádà, ọmọ Élíásíbù olórí àlùfáà jẹ́ àna (o fẹ ọmọbìnrin) Ṣáńbálátì ará a Hórónì. Mo sì lé e jáde kúrò lọ́dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:28 ni o tọ