Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Léfì ni Jéṣúà, Bínúì, Kádímálì, Ṣérébíà, Júdà àti Mátaníyà ẹ̀ni tí òun pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀, ni àkóso orin ìdúpẹ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 12

Wo Nehemáyà 12:8 ni o tọ