Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 12:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì tún yan àwọn olórí Júdà láti gun orí odi náà. Mo sì tún yan àwọn ẹgbẹ́ akọrin ńlá méjì láti dúpẹ́. Àwọn kan yóò gòkè odi lọ sí apá ọ̀tún sí ọ̀nà ibodè Ààtàn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 12

Wo Nehemáyà 12:31 ni o tọ