Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 10:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

gbogbo wọn fi ara mọ́ àwọn arákùnrin wọn, àwọn ọlọ́lá, wọ́n sì fi ègún àti ìbúra dé ara wọn láti máa tẹ̀lé òfin Ọlọ́run tí a fi fún wọn ní ipasẹ̀ Móṣè ìránṣẹ́ Ọlọ́run àti láti pa gbogbo àṣẹ, ìlànà àti òfín Olúwa, wa mọ́ dáadáa.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:29 ni o tọ