Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 10:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn ènìyàn tó kù—àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn aṣọ́nà, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ḿpìlì àti gbogbo àwọn tí wọ́n ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ènìyàn àjèjì nítorí òfin Ọlọ́run, papọ̀ pẹ̀lú ìyàwóo wọn, gbogbo ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn, tí òye yé

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:28 ni o tọ