Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, lórí àwọn okè,awọn ẹsẹ̀ ẹni tí ó mú ìròyin ayọ wá,ẹni tí ó ń kéde àlàáfíà,Ìwọ Júdà, pa àṣẹ rẹ tí ó ní ìrònú mọ́,kí ó sì san àwọn ẹ̀jẹ́ rẹ.Àwọn ènìyàn búburú kì yóò sì gbógun tì ọ́ mọ́;Wọn yóò sì parun pátapáta.

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:15 ni o tọ