Ẹ̀yin sì lé obìnrin àwọn ènìyàn mikúrò nínú ilé ayọ̀ wọn,ẹ̀yin sì ti gba ògo mi,kúrò lọ́wọ́ àwọn ọmọ wọn láéláé.