Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láìpẹ́ àwọn ènìyàn mi dìdebí ọ̀tá sí mi.Ìwọ bọ́ aṣọ ọlọ́rọ̀kúrò lára àwọn tí ń kọjá lọ ní àìléwu,bí àwọn ẹni tí ó padà bọ̀ láti ojú ogun.

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:8 ni o tọ