Nítorí èyí, èmi yóò sì sunkún,èmi yóò sì pohùnréré ẹkún:èmi yóò máa lọ ní ẹsẹ̀ lásán àti ní ihòòhòÈmi yóò ké bí akátá,èmi yóò sì máa dárò bí àwọn ọmọ ògòǹgò.