Fá irun orí rẹ nínú ọ̀fọ̀nítorí àwọn ọmọ rẹ aláìlágbára,sọ ra rẹ̀ di apárí bí ẹyẹ igún,nítorí wọn yóò kúrò lọ́dọ̀ rẹ lọ sí ìgbèkùn.