Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ olùgbé Lákísi,dì kẹ̀kẹ́ mọ́ ẹranko tí ó yára.Òun sì ni ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀sí àwọn ọmọbìnrin Síónì,nítorí a rí ìré-òfin-kọjá Ísírẹ́lì nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Míkà 1

Wo Míkà 1:13 ni o tọ