Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì pa àgbò náà, ó sì mú díẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀, ó tọ́ ọ sí ètí ọ̀tún Árónì, sórí àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún àti ti ẹṣẹ̀ ọ̀tún rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 8

Wo Léfítíkù 8:23 ni o tọ