Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnikẹ́ni bá fọwọ́ kan ohun aláìmọ́ yálà ohun àìmọ́ ti ènìyàn, ẹranko aláìmọ́, ohun àìmọ́ yówù kí ó jẹ́ tàbí ohunkóhun tí ó jẹ́ ìríra, tí ó sì tún jẹ́ ẹran ọrẹ àlàáfíà tó jẹ́ ti Olúwa, a ó gé irú ẹni bẹ́ẹ̀ kúrò lára àwọn ènìyàn rẹ.’ ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:21 ni o tọ