Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:29-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Gbogbo ọkùnrin ní ìdílé àlùfáà ló lè jẹ ẹ́, ó jẹ́ mímọ́ jùlọ.

30. Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ kankan, èyí tí wọ́n bá mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti fi ṣe ètùtù ní ibi mímọ́, sísun ni kí ẹ sun ún.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6