Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ kankan, èyí tí wọ́n bá mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti fi ṣe ètùtù ní ibi mímọ́, sísun ni kí ẹ sun ún.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:30 ni o tọ