Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà tó rú ẹbọ náà ni kí ó jẹ ẹ́, ibi mímọ́ ni kí ó ti jẹ ẹ́, ní àgbàlá àgọ́ ìpàdé.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:26 ni o tọ