Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ Ọkùnrin: ‘Wọ̀nyí ni ìlànà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ kí ẹ sì pa ẹran ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ níwájú Olúwa níbi tí ẹ ti ń pa ẹran ẹbọ sísun, ó jẹ́ mímọ́ jùlọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:25 ni o tọ