Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ni yóò jẹ ìyókù ṣùgbọ́n wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́ láì sí máa wú máa wú ohun tí n mú àkàrà wú nínú rẹ̀ ní ibi mímọ́, ní àgbàlá àgọ́ ìpàdé ni kí wọn ó ti jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:16 ni o tọ