Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó yọ gbogbo ọ̀rá ẹran náà gẹ́gẹ́ bó ṣe yọ ọ̀rá ẹran fún ọrẹ àlàáfíà. Kí àlùfáà sì sun ọ̀rá yìí lórí pẹpẹ bí òórùn dídùn sí Olúwa. Báyìí ni àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún ẹni náà, a ó sì dárí jìn-ín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:31 ni o tọ