Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò sì ti ìka rẹ̀ bọ́ ẹ̀jẹ̀ náà, yóò fi sí orí ìwo pẹpẹ ẹbọ sísun, kí ó sì da ìyókù ẹ̀jẹ̀ náà sí ìṣàlẹ̀ pẹpẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:30 ni o tọ