Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 27:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ẹran tí kò mọ́, nígbà náà ni kí ó rà á padà gẹ́gẹ́ bí ìdíyelé rẹ̀, kí ó sì fi ìdámárùn-ún lé e, tàbí bí a kò bá rà á padà kí ẹ tà á gẹ́gẹ́ bí ìdíyelé rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:27 ni o tọ