Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 26:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èrè oko yín yóò pọ̀ débí pé ẹ ó máa pa ọkà títí di àsìkò ìkórè igi eléso, ẹ̀yin yóò sì máa gbé ní ilé yín láì léwu.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:5 ni o tọ