Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 26:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dá ìpèsè oúnjẹ yín dúró, débi pé: inú àrò kan ni obìnrin mẹ́wàá yóò ti máa ṣe oúnjẹ yín. Òṣùwọ̀n ni wọn yóò fi máa yọ oúnjẹ yín: Ẹ ó jẹ ṣùgbọ́n, ẹ kò ní yó.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:26 ni o tọ