Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 26:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú ogun wá bá yín nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín láti fi gbẹ̀san májẹ̀mú mi tí ẹ kò pa mọ́. Bí ẹ ba sálọ sí ìlú yín fún ààbò: Èmi yóò rán àjàkálẹ̀-àrùn sí ààrín in yín: Àwọn ọ̀ta yín, yóò sì ṣẹ́gun yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:25 ni o tọ