Torí pé ìránṣẹ́ ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́ fún mi. Ìránṣẹ́ mi ni wọ́n, tí mo mú jáde láti Éjíbítì wá. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.