Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ló ni ín. Wọ́n gbọdọ̀ jẹ ẹ́ ní ibi mímọ́ torí pé ó jẹ́ ipa tí ó mọ́ jùlọ ti ìpín wọn ojojúmọ́ nínú ọrẹ tí a fi iná ṣe sí Olúwa.”

Ka pipe ipin Léfítíkù 24

Wo Léfítíkù 24:9 ni o tọ