Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 20:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ọkùnrin tàbí obìnrin tí ó jẹ́ abókúsọ̀rọ̀ tàbí oṣó láàrin yín ni kí ẹ pa. Ẹ sọ wọ́n ní òkúta, ẹ̀jẹ̀ wọn yóò wà lórí wọn.’ ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 20

Wo Léfítíkù 20:27 ni o tọ