Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyòókù nínú ọrẹ ohun jíjẹ náà jẹ́ ti Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó jẹ́ ìpín tí ó mọ́ jùlọ nínú ọrẹ tí a fi iná sun sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:3 ni o tọ