Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó sì gbé lọ fún àwọn ọmọ Árónì tí í se àlùfáà. Àlùfáà yóò bu ẹ̀kúnwọ́ kan nínú ìyẹ̀fun àti òróró náà, pẹ̀lú gbogbo tùràrí kí ó sì sun ún gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìrántí lórí pẹpẹ, ọrẹ tí a fi iná se, àní òórùn dídùn sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:2 ni o tọ