Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó fá gbogbo irun rẹ̀ ní ọjọ́ kéje: irun orí rẹ̀, irungbọ̀n rẹ̀, irun ìpéǹpéjú rẹ̀, àti gbogbo irun rẹ̀ tó kù. Kí ó fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóò sì mọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:9 ni o tọ