Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹni tí a fẹ́ wẹ̀ mọ́ náà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, fá gbogbo irun rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, lẹ́yìn èyí ó ti di mímọ́. Lẹ́yìn náà ó le wá sínú ibùdó ṣùgbọ́n kí ó wà lẹ́yìn àgọ́ rẹ̀ ní ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:8 ni o tọ