Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìbàjẹ́ ara aṣọ: ìbáà ṣe awọ, irun àgùtàn, aṣọ títa, aṣọ híhun tàbí ohun tí a fi awọ ṣe bá di aláwọ̀ ewé tàbí kí ó pupa: èyí jẹ́ ẹ̀tẹ̀ tí ń ràn ká. Ẹ gbọdọ̀ fi hàn fún àlùfáà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:49 ni o tọ