Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbáà ṣe títa tàbí híhun tí ó jẹ́ aṣọ funfun tàbí irun àgùtàn, bóyá àwọ̀ tàbí ohun tí a fi àwọ̀ ṣe.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:48 ni o tọ