Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 11:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọ̀kan nínú wọn bá kú tí wọ́n sì bọ́ sórí nǹkan kan, bí ó ti wù kí irú ohun náà wúlò tó, yóò di aláìmọ́ yálà aṣọ ni a fi ṣe é ni tàbí igi, irun tàbí awọ, ẹ sọ ọ́ sínú omi yóò jẹ́ aláìmọ́ títí ìrọ̀lẹ́ lẹ́yìn náà ni yóò tó di mímọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 11

Wo Léfítíkù 11:32 ni o tọ