Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú gbogbo ẹranko tí ń fi ẹṣẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rìn, àwọn tí ń fi èékánná wọn rìn jẹ́ aláìmọ́ fún yín: Ẹni tí ó bá fọwọ́ kan òkú wọn yóò jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 11

Wo Léfítíkù 11:27 ni o tọ