Mósè sì sọ fún Árónì pé, “Ohun tí Olúwa ń sọ nípa rẹ̀ nìyìí nígbà tó wí p锓 ‘Ní àárin àwọn tó súnmọ́ mi,Èmi yóò fí ara mi hàn ní mímọ́ojú gbogbo ènìyànNí a ó ti bu ọlá fún mi’ ”Árónì sì dákẹ́.