Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ ẹ́ ní ibi mímọ́, nítorí pé òun ni ìpín rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ nínú ẹbọ tí a finá sun sí Olúwa nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni mo ṣe pa á láṣẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:13 ni o tọ