Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì sọ fún Árónì, Élíásárì àti Ítamárì àwọn ọmọ rẹ̀ yóòkù pé “Ẹ mú ẹbọ ohun jíjẹ tó sẹ́kù láti inú ẹbọ àfinásun sí Olúwa, kí ẹ jẹ ẹ́ láì ní ìwúkàrà nínú, lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ nítorí ó jẹ́ mímọ́ jùlọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:12 ni o tọ