Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó gbá apá rẹ̀ méjèèjì mú, kí ó fà á ya, ṣùgbọ́n kí ó má yaá tan pátapáta. Lẹ́yìn náà ni àlùfáà yóò sun ún lórí igi tí ó ń jó lórí pẹpẹ, ọrẹ ẹbọ sísun ni ọrẹ tí a fi iná se, àní òórùn dídùn sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 1

Wo Léfítíkù 1:17 ni o tọ