Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lúù mi yóò súnmọ́ ìlú náà; Nígbà tí àwọn ọkùnrin náà bá jáde sí wa, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe ní ìṣáájú, àwa yóò sì ṣá kúrò níwájú u wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:5 ni o tọ