Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

gẹ́gẹ́ bí Móṣè ìránṣẹ́ Olúwa ti pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Ó sì kọ́ ọ́ gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ nínú Iwé Òfin Móṣè, pẹpẹ odindi òkúta, èyí tí ẹnìkan kò fi ohun èlò irin kàn rí. Wọ́n sì rú ọrẹ ẹbo ṣísun àti ọrẹ àlàáfíà ní orí i rẹ̀ sí Olúwa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:31 ni o tọ