Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé ọba Áì kọ́ orí igi, ó sì fi kalẹ̀ síbẹ̀ títí di ìrọ̀lẹ́. Bí òòrùn sì ti wọ̀ ni Jóṣúà pàṣẹ fún wọn láti sọ òkú rẹ̀ kalẹ̀ kúrò ní orí igi, kí wọn sì wọ́ ọ jù sí àtiwọ ẹnu ibodè ìlú náà. Wọ́n sì kó òkítì òkúta ńlá lé e ní orí, èyí tí ó wà títí di òní yìí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:29 ni o tọ